The beautiful wife of the late Onisemo of Lagos Alhaja Adiat Yetunde Onisemo marks another year of existence with beautiful pictures.
ALSO READ: Photos: Olori Yetunde Arike Onisemo Badged City People Award
Aderonke was born in Epe local government area of Lagos to the family of Agunrege.
She attended Epe Grammar School to obtain her secondary school certificate.
She is a successful entrepreneur and Social Media Influencer.
Olori Yetunde Onisemo is blessed with three (3) children.
Wishes From Friends and Family
Message From Her Father:
#ArikeAde my #sweetDaughter,
Your Birthday is always at hearts and beautiful thoughts fill my mind as I recall this special day.
You have every right and cause to rejoice and be glad indeed, because it is the day the Almighty God has made for you.
God will remove everything that will cause you sorrow and sadness, and multiply everything that will bring peace, joy and happiness to you today, tomorrow and forever.
#SuratulKhaothar!
Ameen kunfayakun!
“Jeje omo Iku,
Jeje omo Arun,
Otoro omo Ejo,
Tipatiele omo Orisala,
Bamigbapoko omo Orunmila.
Awon mararun pejo, won wa npa omo won je.
Iku muu Jeje omo e O paa,
Orunmila ko bawon jee..
Arun muu Jeje omo e O paa,
Orunmila ko bawon jee..
Ejo mu Otoro omo e O paa,
Orunmila ko bawon jee..
Orisala mu Tipatiele omo e O paa,
Orunmila ko bawon jee..
Won pee Orunmila ko mu Bamigbapoko omo e sile,
Orunmila ni rara o…koojo!
Nitori nigbati e nje tiyin,
Orunmila ko bayin jee..
Orunmila ni papa ti a fi sin eja,
Kii ba eja rorun alakeji.
Paapa ti a fi sin eku,
Kii ba eku rorun alakeji.
Bamigbapoko lomo mi #Arikeade..
Eniti o ba ni ko ku,
Iyen a ku kankankan bi ewe ino ti njoni.
Iyen a ku warawara bi omode ti nnoja esinsin,
Iyen a gbe gogo ku bi eku ti ngbe gogo ku,
Iyen a ku bi ejaro se nku pelu enu e malawo-malawo..
Orangun-meji tifi ase si.
Koribe-Kosebe!”
Happy Birthday to you Olori Yetunde Onisemo Of Lagos
KOGÓ! KOGÓ!! LAGOGO ỌJỌ́ ÒNÍ RÓ!!!
AGOGO TÓ Ń KA WÁKÀTÍ ÀTI IṢẸJÚ TÍ KA WÁKÀTÍ RẸ SÍ RERE LÓNÌÍ OOOO…….!
OLORI YÉTÚNDÉ ÒNÍSẸMỌ…..
ÀRÀ Ọ̀TỌ̀ LỌJỌ́ ÒNÍ YÌÍ JẸ́ NÍNÚ AYÉ RẸ….
ORÍIRE ỌJỌ́ ÒNÍ YÌÍ KÒNÍ DI ÌBÀNÚJẸ́….
ỌDỌỌDÚN LÀ Ń RÓRÓGBÓ….
ỌDỌỌDÚN LÀ Ń RÁWÙSÁ….
BỌ́DÚN BÁ JỌ,PẸ̀RẸ̀GÚN A MÁWO TÚTÙ WÁYÉ
WÀ Á NÍPA NÍNÚ OWÓ, ỌMỌ, ÀLÀÁFÍÀ, ÌDÙNNÚ, AYỌ̀, ÀLÀÁFÍÀ ÀTI ÈMÍ GÍGÙN NI ELÉDÙA YÓÒ FI JÍǸKÌ RẸ LÁṢẸ ÈDÙMÀRÈ.
ORIKI EPE
Ọmọ Ẹ̀PẸ́ Alárọ̀ Ògúnmọ́dedé
Ẹ̀PẸ́ olúkù àbàtà…
Kúkúrú lọ́sàán
Gbọ̀n gbọ̀n gbọ̀n lóru
Ọmọ onídà màjẹgi,..màjẹ̀nìyàn
Ọmọ oníta Àgánbú
Àgan ń bú ramú ramù
Ọmọ ijọ́ orò Kána má à wa..
Àna tó bá wá orò a gbé..
Ọmọ igi mẹta níbẹ̀jù
Ọ̀kan ń sowó
Ọ̀kan ń sọmọ
Ọ̀kan yòókù ń so àlárì baba aṣọ…
Ọmọ olóbì kan ò wọ́ọ́wọ́ tiiriwọ́…
Ọmọ olóbì kan ò wọ̀ọ̀wọ̀ tiriwọ̀….
Èyí tó bá dára á wọ̀ sínú ilé wa….
Èyí tí ò dàra a wọ̀ sínú igbó ẹranko burúkú á róhun mújẹ….
Ẹ̀PẸ́ onikùrání…
Kéwú ńlá ni Ìran bàbà tó bí wa lọ́mọ fi ṣẹ̀sìn…
Ọmọ Ẹ̀PẸ́ ẹlẹ́ja tútù…
Ọmọ apẹja fẹ́ja jẹ….
Alade Rashidat Titilayo
A Big Birthday shout out to my Beautiful, Gorgeous, pretty, charming, sweet sixteen Olori Yetunde Onisemo Of lagos ,wishing you many happy returns of ur day long life and prosperity in good health, wealth, joy, peace of mind,success n may u live long to eat the fruit of ur labour in Jesus name Amen… Age gracefully ma’am
Alhaja Abike Fausia
Alhamdulilah Rabil Aliam, happy birthday🎂 to you Olori Yetunde Onisemo Oflagos. I pray🤲 all what you lay your hands on shall prosper in mighty name of Allah 🙏. Have fun is your day Olori tiwa nidumota, igba odun iseju kan ni
Azeez Afolashade
I Wish you the biggest joy and happiness on this special day, godmother! Hope the coming years will bring you something new and full of good emotions. You are so cute and lovely person that I just need to be like you. Love you, my woman.Happy birthday momma,thanks for all the love nd care you will always remain in my heart egbon mi oninu ire,i love you endlessly Arike temi,you re love today,tomorrow nd forever❤❤❤😍😍😍enjoy your special day ma💃💃💃💃
Funke Kayode
The day that you have been waiting for is finally here. The day of celebrations and fun, the day of smiles and sweets. I wish you a birthday full of joy and happiness. May you make sweet and special memories throughout the day, and enjoy it to the fullest. May the lights of luck and glory always shine on you….Congratulations my darling Olori ti o sure
Adejat Ajoke Odesanya
Happy birthday to beautiful olori Arike llnp more fruitful years ahead keep living darling dis will never be ur last celebration on earth,u will never know sorrow throughout ur life time.
More message still coming.. Drop your wishes in the comment box.