Historical Background and Traditional Chant of Offa People

OFFA


Offa is a city located in Kwara state. Though the Indigines are predominantly Yorubas but geographically it is not situated in South-West like most Yoruba speaking states. It is located in Central Nigeria.

It is known for the cultivation of sweet potatoes (anömö or odunkun) which also formed part of the eulogy (oriki) of the Town.


Lagos State Executive Council Celebrate The Dutiful, Diligent, Dedicated, Digital and Devoted Deputy Governor On His Birth Anniversary


The ancient tradition which Offa is known for is Wrestling. This came to being as a result of the long period of WRESTLE that occurred between two brothers who on the course of sharing a roasted potato, which was not equally divided in the farm.

These two brothers were alone in the farm and there was nobody to separate them aside the ridges and shaft of corn on the farm.


A Finster is a Brave and Inteligent Woman Who Encourage Other’s To Speak


Offa was settled around AD 1000 by the Yorubas. The Offa race/settlements can be traced to Osun and Oyo state today, also to Cote d’Ivoire.

Oriki Offa

  • ÌYÈRÚ ÒKÍN
  • OLÓFÀ MÖJÒ
  • OLÁLOMÍ OMO A B’IŞU JOOKO
  • OMO IJA KAN, IJA KAN
  • TI WON JA L’OFA
  • WON LO Ş’OJU TANI?
  • WON LO Ş’OJU EBÈ
  • WON LO Ş’OJU PORO
  • NIWAJU OLÓKO
  • Ì BÁ Ş’OJU OLOFA MOJO
  • A TI PE WON RAN N’ÍŞÉ
  • OMO LÀÁREE
  • OMO BÙÚREE
  • IKAN O GBODO JU KAN
  • B’IKAN BA JU KAN
  • N’ÍLÉ OLOFA MOJO
  • OGUN LÓÚN DA S’ÍLÉ BABA WON
  • IJAKADI L’ORÒ OFFA
  • ÀNÒMÓ LOUNJE ÒFÀ
  • KAN BA MI W’ÁNÒMÓ WA
  • KIN RI UN P’ANU
  • A LU KÓSÓ OLÓFÀ EGBEJE
  • A LU BÈMBÉ OLOFA EGBÈFÀ
  • A LU ŞÍKÍÑJÌRÍN OLOFA EGBEEDOGUN
  • AKĘBAJĘ LO BA OMO OLOFA MÖJÖ JĘ N’ÍJÓSÍ
  • TO FI JE PE ĘRU MÖ ILÁ KA J’OMO LÖ
  • OFFA Ò M’ÒKÁ
  • ERÚ Ę LÓ MÒ Ó KÁ
  • LALOMI
  • ÈMI Ò NÍ KI OLÓFÀ TÍTÍ
  • KÍN Ş’ÉPÈ SÖ RA MI.
  • OMO A B’IŞU J’ARA GBADA…

Long Version of The Congnomen of Offa People

Ede okin olofa mojo, olofa omo olalomi ab’isu joko ijakadi loro Offa, ija peki abe owula, bi ko ba se oju ebe l’Offa, as óju poro l’oko, iba soju oloko iba la won, osoju agunmona  l’Offa, O soju agbele yarara, o soju aporuba ka ‘ko.

kinni se kagun-kakanrun ni ile oba, oka ni se kagun kankanrun, Agbado ni agun-mona l’Offa, Eree ni agbele yarara, isu ni aporubu ka ‘ko, omo odi meta mete meta me ti nbe l’Offa mojo, odi iwaju  ti olusan, t’ehin ni se ti olumiran, t’arin gungun ni se ti olugbenise omo ayejin, omo odo meta meta ti ntun nbe l’Offa mojo.

  1. Okan  ni apa erinla boo un ki oun dókun,
  2. Okan ni apa agbo boo un ki oun d’osa,
  3. okan ni ki apa akuko gagara boo un ki oun di agunloko l’Offa oba ni okookan.

Offa ti t’agbo ra, ododo won ti to erinla pa sugbon ni okan ba d’okun, ti okan ba d’osa nibo ni ako omo yebiye wonyisi. Eyi ti won wapa akuko ganga boo a ni owa di agunloko l’Offa olofa omo la ki Offa kun tele, olalomi ede okin olofa mojo Olofa Omo laare ki o dogba, okan ko gbodo ju kan bi okan ba ju kan, oba ni ko won roro.

Oba ko wa ri ti awa d’iran peki mob a odofin dimu, mose ojomu Karin, mo fi ehin saawo ra’le l’Offa o m’aka Arijasoro, olalomi lo laare. Offa o m’aka egun wole l’Offa to ju ti omo okuta meta nsese, okan ko mi lese okansemi  pele, okan semi nrora, Okan n’gbati emi mona, kinni mo wade ilu ete okan n’gbati emi ko mona kinin.

Mo wa de ilu ero Okan n’gbati emi mona, kinni mo wa de ilu awon-won ni ile olalomi ti omi ti won ti oju lo Ede Okin timo ri okin bamuiti mofi abata sin ese l’Offa ti mo wari abelenje boju mo la k’Offa okun keekee Aral ale, olalomi omo orubo nla ti osubu l’aro papa ni ohun bata, oki mi o nla mi, olalomi tani osehun ninu ara won ileyi ko gbaye

A ko lo si loffa nigbati iloffa o gba wa a ko lo s’Offa oro nigbati Offa oro o gba wa, a ko los’Offa irese nigbati Offa irese ko gba wa, ako losi igbolutu  nigbati igbolutu ko gba wa mo, a tun pada si Offa Eesun nigbati Offa eesun o gbawa mo ni awa kowa si Offa Arinlolu olofa se pele o aro ko ya bumu.

How To Earn Daily Income With These 4 Home Base Snacks as a Student

Ede olele aro ko ya buwe Ede olele aro ko ya buboju igun ni a rini a dasa geru, Akala nia rini a sasa l’edo olofa imole ni arin ni a wa dasa lami labe lapa se olofa lo ni omo , ko si Eku ti oju Offa o di oyo olofa ni oni omo gbengbeleku ni ara yoku nsan ni nwon ki olalomi iyeru okin.

%d bloggers like this: